ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 10:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àmọ́, màá sọ àwọn nǹkan tí a kọ sínú ìwé òtítọ́ fún ọ. Kò sí ẹni tó ń tì mí lẹ́yìn gbágbáágbá nínú àwọn nǹkan yìí, àfi Máíkẹ́lì,+ olórí yín.+

  • Dáníẹ́lì 12:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “Ní àkókò yẹn, Máíkẹ́lì*+ máa dìde, ọmọ aládé ńlá+ tó dúró nítorí àwọn èèyàn rẹ.* Àkókò wàhálà máa wáyé, èyí tí irú rẹ̀ kò wáyé rí látìgbà tí orílẹ̀-èdè ti wà títí di àkókò yẹn. Ní àkókò yẹn, àwọn èèyàn rẹ máa yè bọ́,+ gbogbo àwọn tí orúkọ wọn wà nínú ìwé.+

  • Júùdù 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Kódà nígbà tí Máíkẹ́lì+ olú áńgẹ́lì+ ń bá Èṣù fa ọ̀rọ̀, tí wọ́n sì ń jiyàn nípa òkú Mósè,+ kò jẹ́ dá a lẹ́jọ́, kò sì sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí i,+ àmọ́ ó sọ fún un pé: “Kí Jèhófà* bá ọ wí.”+

  • Ìfihàn 12:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ogun sì bẹ́ sílẹ̀ ní ọ̀run: Máíkẹ́lì*+ àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ bá dírágónì náà jà, dírágónì náà àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sì jà, 8 àmọ́ wọn ò borí,* kò sì sí àyè kankan fún wọn mọ́ ní ọ̀run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́