Dáníẹ́lì 11:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àwọn ọmọ ogun* máa dìde, láti ọ̀dọ̀ rẹ̀; wọ́n máa sọ ibi mímọ́, ibi ààbò, di aláìmọ́,+ wọ́n sì máa mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* kúrò.+ “Wọ́n máa gbé ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀.+ Máàkù 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Àmọ́ tí ẹ bá tajú kán rí ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro,+ tó dúró ní ibi tí kò yẹ (kí òǹkàwé lo òye), nígbà náà, kí àwọn tó wà ní Jùdíà bẹ̀rẹ̀ sí í sá lọ sí àwọn òkè.+
31 Àwọn ọmọ ogun* máa dìde, láti ọ̀dọ̀ rẹ̀; wọ́n máa sọ ibi mímọ́, ibi ààbò, di aláìmọ́,+ wọ́n sì máa mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* kúrò.+ “Wọ́n máa gbé ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀.+
14 “Àmọ́ tí ẹ bá tajú kán rí ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro,+ tó dúró ní ibi tí kò yẹ (kí òǹkàwé lo òye), nígbà náà, kí àwọn tó wà ní Jùdíà bẹ̀rẹ̀ sí í sá lọ sí àwọn òkè.+