-
Dáníẹ́lì 7:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 “Mo fẹ́ mọ̀ sí i nípa ẹranko kẹrin, tó yàtọ̀ sí gbogbo àwọn yòókù; ó ń bani lẹ́rù lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀, ó ní eyín irin àti èékánná bàbà, ó ń jẹ nǹkan run, ó ń fọ́ nǹkan túútúú, ó sì ń fi ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ ohun tó ṣẹ́ kù mọ́lẹ̀;+
-