Dáníẹ́lì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àgbà òṣìṣẹ́ láàfin sì fún wọn ní orúkọ;* ó pe Dáníẹ́lì ní Bẹtiṣásárì,+ ó pe Hananáyà ní Ṣádírákì, ó pe Míṣáẹ́lì ní Méṣákì, ó sì pe Asaráyà ní Àbẹ́dínígò.+ Dáníẹ́lì 2:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Bí Dáníẹ́lì sì ṣe béèrè, ọba yan Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò+ láti máa bójú tó ìpínlẹ̀* Bábílónì, àmọ́ Dáníẹ́lì ń ṣiṣẹ́ ní ààfin ọba.
7 Àgbà òṣìṣẹ́ láàfin sì fún wọn ní orúkọ;* ó pe Dáníẹ́lì ní Bẹtiṣásárì,+ ó pe Hananáyà ní Ṣádírákì, ó pe Míṣáẹ́lì ní Méṣákì, ó sì pe Asaráyà ní Àbẹ́dínígò.+
49 Bí Dáníẹ́lì sì ṣe béèrè, ọba yan Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò+ láti máa bójú tó ìpínlẹ̀* Bábílónì, àmọ́ Dáníẹ́lì ń ṣiṣẹ́ ní ààfin ọba.