Dáníẹ́lì 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní ọdún kejì tí Nebukadinésárì di ọba, ó lá àwọn àlá kan, ọkàn* rẹ̀ ò sì balẹ̀ rárá+ débi pé kò rí oorun sùn.
2 Ní ọdún kejì tí Nebukadinésárì di ọba, ó lá àwọn àlá kan, ọkàn* rẹ̀ ò sì balẹ̀ rárá+ débi pé kò rí oorun sùn.