Dáníẹ́lì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àgbà òṣìṣẹ́ láàfin sì fún wọn ní orúkọ;* ó pe Dáníẹ́lì ní Bẹtiṣásárì,+ ó pe Hananáyà ní Ṣádírákì, ó pe Míṣáẹ́lì ní Méṣákì, ó sì pe Asaráyà ní Àbẹ́dínígò.+
7 Àgbà òṣìṣẹ́ láàfin sì fún wọn ní orúkọ;* ó pe Dáníẹ́lì ní Bẹtiṣásárì,+ ó pe Hananáyà ní Ṣádírákì, ó pe Míṣáẹ́lì ní Méṣákì, ó sì pe Asaráyà ní Àbẹ́dínígò.+