Hósíà 8:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí wọ́n ti lọ sí Ásíríà,+ bíi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ inú igbó tó dá wà. Éfúrémù ti lọ gba àwọn aṣẹ́wó láti fi ṣe olólùfẹ́.+ Hósíà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Ẹ̀fúùfù ni Éfúrémù fi ṣe oúnjẹ. Ó sì ń sá tẹ̀ lé ẹ̀fúùfù ìlà oòrùn láti àárọ̀ ṣúlẹ̀. Ó mú kí irọ́ àti ìwà ipá pọ̀ sí i. Ó bá Ásíríà dá májẹ̀mú,+ ó sì gbé òróró lọ sí Íjíbítì.+
9 Nítorí wọ́n ti lọ sí Ásíríà,+ bíi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ inú igbó tó dá wà. Éfúrémù ti lọ gba àwọn aṣẹ́wó láti fi ṣe olólùfẹ́.+
12 “Ẹ̀fúùfù ni Éfúrémù fi ṣe oúnjẹ. Ó sì ń sá tẹ̀ lé ẹ̀fúùfù ìlà oòrùn láti àárọ̀ ṣúlẹ̀. Ó mú kí irọ́ àti ìwà ipá pọ̀ sí i. Ó bá Ásíríà dá májẹ̀mú,+ ó sì gbé òróró lọ sí Íjíbítì.+