Émọ́sì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Asáré tete kò ní rí ibi sá sí,+Alágbára kò ní lókun mọ́,Kò sì ní sí jagunjagun tó máa lè gba ẹ̀mí* ara rẹ̀ là.
14 Asáré tete kò ní rí ibi sá sí,+Alágbára kò ní lókun mọ́,Kò sì ní sí jagunjagun tó máa lè gba ẹ̀mí* ara rẹ̀ là.