Hósíà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Irọ́ ni Éfúrémù ń pa fún mi ṣáá,Ẹ̀tàn sì ni ilé Ísírẹ́lì ń ṣe sí mi nígbà gbogbo.+ Àmọ́ Júdà ṣì ń bá Ọlọ́run rìn,Ó sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ẹni Mímọ́ Jù Lọ.”+
12 “Irọ́ ni Éfúrémù ń pa fún mi ṣáá,Ẹ̀tàn sì ni ilé Ísírẹ́lì ń ṣe sí mi nígbà gbogbo.+ Àmọ́ Júdà ṣì ń bá Ọlọ́run rìn,Ó sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ẹni Mímọ́ Jù Lọ.”+