Àìsáyà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.”
3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.”