Àìsáyà 59:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 A ti ṣẹ̀, a sì ti sẹ́ Jèhófà;A ti kẹ̀yìn sí Ọlọ́run wa,A ti sọ̀rọ̀ nípa ìnilára àti ọ̀tẹ̀;+A ti lóyún irọ́, a sì ti sọ̀rọ̀ èké kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ látinú ọkàn.+
13 A ti ṣẹ̀, a sì ti sẹ́ Jèhófà;A ti kẹ̀yìn sí Ọlọ́run wa,A ti sọ̀rọ̀ nípa ìnilára àti ọ̀tẹ̀;+A ti lóyún irọ́, a sì ti sọ̀rọ̀ èké kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ látinú ọkàn.+