Hósíà 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ṣùgbọ́n bí èèyàn lásán-làsàn, wọ́n ti tẹ májẹ̀mú lójú.+ Wọ́n ti hùwà àìṣòótọ́ sí mi ní ilẹ̀ wọn.