-
Hósíà 10:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ẹ̀rù máa ba àwọn tó ń gbé ní Samáríà torí òrìṣà ọmọ màlúù tó wà ní Bẹti-áfénì.+
Àwọn èèyàn rẹ̀ máa ṣọ̀fọ̀ rẹ̀,
Bẹ́ẹ̀ ni àwọn àlùfáà ọlọ́run àjèjì ibẹ̀, tó máa ń yọ̀ lórí rẹ̀ àti ògo rẹ̀, máa ṣọ̀fọ̀,
Nítorí pé a ó mú un kúrò lọ́dọ̀ wọn lọ sí ìgbèkùn.
6 A ó mú un wá sí Ásíríà, láti fi ta ọba ńlá lọ́rẹ.+
Ojú á ti Éfúrémù,
Ìtìjú á sì bá Ísírẹ́lì nítorí ìmọ̀ràn tó tẹ̀ lé.+
-