Ìsíkíẹ́lì 28:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Ọmọ èèyàn, kọ orin arò* nípa ọba Tírè, kí o sì sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “O jẹ́ àpẹẹrẹ ohun tó pé,*Ọgbọ́n kún inú rẹ,+ ẹwà rẹ ò sì lábùlà.+
12 “Ọmọ èèyàn, kọ orin arò* nípa ọba Tírè, kí o sì sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “O jẹ́ àpẹẹrẹ ohun tó pé,*Ọgbọ́n kún inú rẹ,+ ẹwà rẹ ò sì lábùlà.+