2 Àwọn Ọba 23:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó tún wó pẹpẹ tó wà ní Bẹ́tẹ́lì, ìyẹn ibi gíga tí Jèróbóámù ọmọ Nébátì kọ́, tó mú kí Ísírẹ́lì ṣẹ̀.+ Lẹ́yìn tó wó pẹpẹ yẹn àti ibi gíga náà, ó dáná sun ibi gíga náà, ó lọ̀ ọ́ kúnná, ó sì sun òpó òrìṣà*+ náà.
15 Ó tún wó pẹpẹ tó wà ní Bẹ́tẹ́lì, ìyẹn ibi gíga tí Jèróbóámù ọmọ Nébátì kọ́, tó mú kí Ísírẹ́lì ṣẹ̀.+ Lẹ́yìn tó wó pẹpẹ yẹn àti ibi gíga náà, ó dáná sun ibi gíga náà, ó lọ̀ ọ́ kúnná, ó sì sun òpó òrìṣà*+ náà.