Jóẹ́lì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà yóò sì fi ohùn rara sọ̀rọ̀ láti Síónì,Yóò gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù. Ọ̀run àti ayé yóò sì mì jìgìjìgì;Àmọ́ Jèhófà yóò jẹ́ ibi ààbò fún àwọn èèyàn rẹ̀,+Odi ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
16 Jèhófà yóò sì fi ohùn rara sọ̀rọ̀ láti Síónì,Yóò gbé ohùn rẹ̀ sókè láti Jerúsálẹ́mù. Ọ̀run àti ayé yóò sì mì jìgìjìgì;Àmọ́ Jèhófà yóò jẹ́ ibi ààbò fún àwọn èèyàn rẹ̀,+Odi ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.