-
Ìsíkíẹ́lì 20:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “‘“Àmọ́ àwọn ọmọ náà bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+ Wọn ò tẹ̀ lé àwọn àṣẹ mi mọ́, wọn ò tẹ̀ lé àwọn ìdájọ́ mi, wọn ò sì rìn nínú rẹ̀, èyí tó lè mú kí ẹni tó bá ń pa wọ́n mọ́ wà láàyè. Wọ́n sọ àwọn sábáàtì mi di aláìmọ́. Torí náà, mo pinnu pé màá bínú sí wọn, inú mi á sì ru sí wọn gidigidi ní aginjù.+
-