Jeremáyà 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nígbà ayé Ọba Jòsáyà,+ Jèhófà sọ fún mi pé: “‘Ṣé o ti rí ohun tí Ísírẹ́lì aláìṣòótọ́ ṣe? Ó ti lọ sórí gbogbo òkè ńlá àti sábẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀, kí ó lè ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+
6 Nígbà ayé Ọba Jòsáyà,+ Jèhófà sọ fún mi pé: “‘Ṣé o ti rí ohun tí Ísírẹ́lì aláìṣòótọ́ ṣe? Ó ti lọ sórí gbogbo òkè ńlá àti sábẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀, kí ó lè ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+