2 Àwọn Ọba 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní ọdún kejìdínlógójì Asaráyà+ ọba Júdà, Sekaráyà+ ọmọ Jèróbóámù di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà, ó sì fi oṣù mẹ́fà ṣàkóso. 2 Àwọn Ọba 15:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìgbà náà ni Ṣálúmù ọmọ Jábéṣì dìtẹ̀ mọ́ ọn, ó sì pa á+ ní Íbíléámù.+ Lẹ́yìn tó pa á, ó jọba ní ipò rẹ̀.
8 Ní ọdún kejìdínlógójì Asaráyà+ ọba Júdà, Sekaráyà+ ọmọ Jèróbóámù di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà, ó sì fi oṣù mẹ́fà ṣàkóso.
10 Ìgbà náà ni Ṣálúmù ọmọ Jábéṣì dìtẹ̀ mọ́ ọn, ó sì pa á+ ní Íbíléámù.+ Lẹ́yìn tó pa á, ó jọba ní ipò rẹ̀.