Àìsáyà 12:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ké jáde, kí o sì kígbe ayọ̀, ìwọ* tó ń gbé ní Síónì,Torí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì tóbi láàárín rẹ.” Sekaráyà 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn ti Éfúrémù yóò dà bíi jagunjagun tó lákíkanjú,Ọkàn wọn yóò sì yọ̀ bíi pé wọ́n mu wáìnì.+ Àwọn ọmọ wọn á rí èyí, inú wọn á sì dùn;Ọkàn wọn máa yọ̀ torí Jèhófà.+
7 Àwọn ti Éfúrémù yóò dà bíi jagunjagun tó lákíkanjú,Ọkàn wọn yóò sì yọ̀ bíi pé wọ́n mu wáìnì.+ Àwọn ọmọ wọn á rí èyí, inú wọn á sì dùn;Ọkàn wọn máa yọ̀ torí Jèhófà.+