Ìṣe 2:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Èmi yóò fi àwọn ohun ìyanu* hàn ní ọ̀run lókè àti àwọn iṣẹ́ àmì ní ayé nísàlẹ̀, ẹ̀jẹ̀ àti iná pẹ̀lú èéfín tó ṣú bolẹ̀. 20 Oòrùn yóò ṣókùnkùn, òṣùpá yóò sì di ẹ̀jẹ̀, kí ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ olókìkí Jèhófà* tó dé.
19 Èmi yóò fi àwọn ohun ìyanu* hàn ní ọ̀run lókè àti àwọn iṣẹ́ àmì ní ayé nísàlẹ̀, ẹ̀jẹ̀ àti iná pẹ̀lú èéfín tó ṣú bolẹ̀. 20 Oòrùn yóò ṣókùnkùn, òṣùpá yóò sì di ẹ̀jẹ̀, kí ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ olókìkí Jèhófà* tó dé.