-
Ẹ́kísódù 10:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Na ọwọ́ rẹ sí ọ̀run, kí òkùnkùn lè bo ilẹ̀ Íjíbítì, òkùnkùn tó máa ṣú biribiri débi pé á fẹ́rẹ̀ẹ́ ṣeé fọwọ́ bà.” 22 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Mósè na ọwọ́ rẹ̀ sí ọ̀run, òkùnkùn biribiri sì ṣú bo gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì fún ọjọ́ mẹ́ta.+
-