Diutarónómì 28:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 O máa fẹ́ obìnrin sọ́nà, àmọ́ ọkùnrin míì á fipá bá a lò pọ̀. O máa kọ́ ilé, àmọ́ o ò ní gbé ibẹ̀.+ O máa gbin àjàrà, àmọ́ o ò ní rí i lò.+
30 O máa fẹ́ obìnrin sọ́nà, àmọ́ ọkùnrin míì á fipá bá a lò pọ̀. O máa kọ́ ilé, àmọ́ o ò ní gbé ibẹ̀.+ O máa gbin àjàrà, àmọ́ o ò ní rí i lò.+