Míkà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Mò ń gbèrò àjálù kan sí ìdílé yìí,+ ẹ kò sì ní yè bọ́.*+ Ẹ kò ní lè gbéra ga mọ́,+ torí àkókò àjálù ló máa jẹ́.+
3 Torí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Mò ń gbèrò àjálù kan sí ìdílé yìí,+ ẹ kò sì ní yè bọ́.*+ Ẹ kò ní lè gbéra ga mọ́,+ torí àkókò àjálù ló máa jẹ́.+