-
2 Kíróníkà 19:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ó sọ fún àwọn onídàájọ́ náà pé: “Ẹ fiyè sí ohun tí ẹ̀ ń ṣe, nítorí kì í ṣe èèyàn lẹ̀ ń ṣojú fún tí ẹ bá ń dájọ́, Jèhófà ni, ó sì wà pẹ̀lú yín nígbà tí ẹ bá ń ṣe ìdájọ́.+
-
-
Émọ́sì 5:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo ṣàn wálẹ̀ bí omi,+
Àti òdodo bí odò tó ń ṣàn nígbà gbogbo.
-