Àìsáyà 5:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn tó ń fi okùn ẹ̀tàn fa ẹ̀bi wọn lọ gbé,Tí wọ́n sì ń fi okùn kẹ̀kẹ́ ẹṣin fa ẹ̀ṣẹ̀ wọn;19 Àwọn tó ń sọ pé: “Kó jẹ́ kí iṣẹ́ Rẹ̀ yára kánkán;Kó tètè dé, ká lè rí i. Kí ohun tí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ní lọ́kàn* ṣẹ,Ká lè mọ̀ ọ́n!”+
18 Àwọn tó ń fi okùn ẹ̀tàn fa ẹ̀bi wọn lọ gbé,Tí wọ́n sì ń fi okùn kẹ̀kẹ́ ẹṣin fa ẹ̀ṣẹ̀ wọn;19 Àwọn tó ń sọ pé: “Kó jẹ́ kí iṣẹ́ Rẹ̀ yára kánkán;Kó tètè dé, ká lè rí i. Kí ohun tí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì ní lọ́kàn* ṣẹ,Ká lè mọ̀ ọ́n!”+