-
Émọ́sì 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 ‘Ẹ gbọ́, kí ẹ sì kìlọ̀ fún* ilé Jékọ́bù,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
-
-
Émọ́sì 3:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Màá wó ilé ìgbà òtútù àti ilé ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn lulẹ̀.’
-