1 Àwọn Ọba 22:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ní ti ìyókù ìtàn Áhábù àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti ilé* tó fi eyín erin kọ́+ àti gbogbo ìlú tí ó kọ́, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn àwọn ọba Ísírẹ́lì?
39 Ní ti ìyókù ìtàn Áhábù àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti ilé* tó fi eyín erin kọ́+ àti gbogbo ìlú tí ó kọ́, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn àwọn ọba Ísírẹ́lì?