Àìsáyà 22:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ dípò ìyẹn, wọ́n ń yọ̀, inú wọn sì ń dùn,Wọ́n ń pa màlúù, wọ́n sì ń dúńbú àgùntàn,Wọ́n ń jẹ ẹran, wọ́n sì ń mu wáìnì.+ ‘Ẹ jẹ́ ká máa jẹ, ká sì máa mu, torí ọ̀la la máa kú.’”+
13 Àmọ́ dípò ìyẹn, wọ́n ń yọ̀, inú wọn sì ń dùn,Wọ́n ń pa màlúù, wọ́n sì ń dúńbú àgùntàn,Wọ́n ń jẹ ẹran, wọ́n sì ń mu wáìnì.+ ‘Ẹ jẹ́ ká máa jẹ, ká sì máa mu, torí ọ̀la la máa kú.’”+