Àìsáyà 10:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Àháà! ará Ásíríà,+Ọ̀pá tí mo fi ń fi ìbínú mi hàn+Àti ọ̀pá ọwọ́ wọn tí mo fi ń báni wí! 6 Màá rán an sí orílẹ̀-èdè apẹ̀yìndà,+Sí àwọn èèyàn tó múnú bí mi;Màá pàṣẹ fún un pé kó kó nǹkan púpọ̀ àti ẹrù ogun tó pọ̀,Kó sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ bí ẹrẹ̀ lójú ọ̀nà.+
5 “Àháà! ará Ásíríà,+Ọ̀pá tí mo fi ń fi ìbínú mi hàn+Àti ọ̀pá ọwọ́ wọn tí mo fi ń báni wí! 6 Màá rán an sí orílẹ̀-èdè apẹ̀yìndà,+Sí àwọn èèyàn tó múnú bí mi;Màá pàṣẹ fún un pé kó kó nǹkan púpọ̀ àti ẹrù ogun tó pọ̀,Kó sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ bí ẹrẹ̀ lójú ọ̀nà.+