Ìsíkíẹ́lì 26:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọmọ èèyàn, torí pé Tírè ti sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé,+ ‘Àháà! Wọ́n ti fọ́ ilẹ̀kùn àwọn èèyàn náà!+ Gbogbo nǹkan á di tèmi, màá sì wá di ọlọ́rọ̀ torí ó ti di ahoro báyìí’;
2 “Ọmọ èèyàn, torí pé Tírè ti sọ nípa Jerúsálẹ́mù pé,+ ‘Àháà! Wọ́n ti fọ́ ilẹ̀kùn àwọn èèyàn náà!+ Gbogbo nǹkan á di tèmi, màá sì wá di ọlọ́rọ̀ torí ó ti di ahoro báyìí’;