Émọ́sì 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ má ṣe wá Bẹ́tẹ́lì kiri,+Ẹ má lọ sí Gílígálì,+ ẹ má sì kọjá sí Bíá-ṣébà,+Torí ó dájú pé Gílígálì máa lọ sí ìgbèkùn,+Bẹ́tẹ́lì á sì di asán.*
5 Ẹ má ṣe wá Bẹ́tẹ́lì kiri,+Ẹ má lọ sí Gílígálì,+ ẹ má sì kọjá sí Bíá-ṣébà,+Torí ó dájú pé Gílígálì máa lọ sí ìgbèkùn,+Bẹ́tẹ́lì á sì di asán.*