Nọ́ńbà 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọkùnrin tàbí obìnrin kan bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ pàtàkì pé òun fẹ́ di Násírì*+ fún Jèhófà, Àwọn Onídàájọ́ 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wò ó! O máa lóyún, o sì máa bí ọmọkùnrin kan, abẹ kankan ò gbọ́dọ̀ kàn án lórí,+ torí Násírì Ọlọ́run ni ọmọ náà máa jẹ́ látìgbà tí o bá ti bí i,* òun ló sì máa ṣáájú láti gba Ísírẹ́lì sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn Filísínì.”+
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọkùnrin tàbí obìnrin kan bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ pàtàkì pé òun fẹ́ di Násírì*+ fún Jèhófà,
5 Wò ó! O máa lóyún, o sì máa bí ọmọkùnrin kan, abẹ kankan ò gbọ́dọ̀ kàn án lórí,+ torí Násírì Ọlọ́run ni ọmọ náà máa jẹ́ látìgbà tí o bá ti bí i,* òun ló sì máa ṣáájú láti gba Ísírẹ́lì sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn Filísínì.”+