ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 20:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Torí náà, mo sọ pé: “Mi ò ní sọ nípa rẹ̀ mọ́,

      Mi ò sì ní sọ̀rọ̀ ní orúkọ rẹ̀ mọ́.”+

      Àmọ́ nínú ọkàn mi, ńṣe ló dà bí iná tó ń jó, tí wọ́n sé mọ́ inú egungun mi,

      Mi ò lè pa á mọ́ra mọ́,

      Mi ò sì lè fara dà á mọ́.+

  • Émọ́sì 7:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ìgbà náà ni Émọ́sì dá Amasááyà lóhùn pé: “Wòlíì kọ́ ni mí tẹ́lẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni èmi kì í ṣe ọmọ wòlíì; olùṣọ́ agbo ẹran ni mí,+ mo sì máa ń tọ́jú igi ọ̀pọ̀tọ́ síkámórè.* 15 Àmọ́ Jèhófà sọ fún mi pé kí n má ṣe da agbo ẹran mọ́, Jèhófà sì sọ fún mi pé, ‘Lọ, sọ tẹ́lẹ̀ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’+

  • Ìṣe 4:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́, Pétérù àti Jòhánù fún wọn lésì pé: “Ẹ̀yin náà ẹ sọ, tó bá tọ́ lójú Ọlọ́run pé ká fetí sí yín dípò ká fetí sí Ọlọ́run. 20 Àmọ́ ní tiwa, a ò lè ṣàì sọ ohun tí a ti rí tí a sì ti gbọ́.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́