1 Àwọn Ọba 19:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà sọ fún un pé: “Pa dà, lọ sí aginjù Damásíkù. Tí o bá débẹ̀, fi òróró yan Hásáẹ́lì+ ṣe ọba lórí Síríà.
15 Jèhófà sọ fún un pé: “Pa dà, lọ sí aginjù Damásíkù. Tí o bá débẹ̀, fi òróró yan Hásáẹ́lì+ ṣe ọba lórí Síríà.