Hósíà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí Éfúrémù ti mọ pẹpẹ púpọ̀ kó lè máa dẹ́ṣẹ̀.+ Àwọn pẹpẹ náà ló sì fi ń dẹ́ṣẹ̀.+ Hósíà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n ń fi ẹran rúbọ sí mi, wọ́n sì jẹ ẹran náà,Ṣùgbọ́n inú Jèhófà kò dùn sí ẹbọ wọn.+ Ó máa rántí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, á sì fìyà jẹ wọ́n nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Wọ́n ti yíjú* sí Íjíbítì.+
13 Wọ́n ń fi ẹran rúbọ sí mi, wọ́n sì jẹ ẹran náà,Ṣùgbọ́n inú Jèhófà kò dùn sí ẹbọ wọn.+ Ó máa rántí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, á sì fìyà jẹ wọ́n nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+ Wọ́n ti yíjú* sí Íjíbítì.+