-
1 Àwọn Ọba 18:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Áhábù wá sọ fún Ọbadáyà pé: “Lọ káàkiri ilẹ̀ yìí, sí gbogbo ìsun omi àti gbogbo àfonífojì. Bóyá a lè rí koríko tútù, tí a máa fún àwọn ẹṣin àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* wa, kí gbogbo àwọn ẹran wa má bàa kú.”
-