Jeremáyà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà tó bá fọhùn,Omi ojú ọ̀run á ru gùdù,+Á sì mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé.+ Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò,Ó sì ń mú ẹ̀fúùfù wá láti inú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+
13 Nígbà tó bá fọhùn,Omi ojú ọ̀run á ru gùdù,+Á sì mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé.+ Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò,Ó sì ń mú ẹ̀fúùfù wá láti inú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+