Jóẹ́lì 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n ń ṣẹ́ kèké torí àwọn èèyàn mi;+Wọ́n ń fi ọmọ wọn ọkùnrin dúró kí wọ́n lè gbé aṣẹ́wó,Wọ́n sì ń ta àwọn ọmọ wọn obìnrin torí àtimu wáìnì.
3 Wọ́n ń ṣẹ́ kèké torí àwọn èèyàn mi;+Wọ́n ń fi ọmọ wọn ọkùnrin dúró kí wọ́n lè gbé aṣẹ́wó,Wọ́n sì ń ta àwọn ọmọ wọn obìnrin torí àtimu wáìnì.