ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 24:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “Tí o bá kórè èso àjàrà inú ọgbà rẹ, o ò gbọ́dọ̀ pa dà lọ kó àwọn èso tó bá ṣẹ́ kù. Fi sílẹ̀ níbẹ̀ fún àjèjì, ọmọ aláìníbaba àti opó.

  • Jeremáyà 49:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Bí àwọn tó ń kó èso àjàrà jọ bá wá bá ọ,

      Ṣé wọn ò ní ṣẹ́ díẹ̀ kù fáwọn tó ń pèéṣẹ́?*

      Bí àwọn olè bá wá bá ọ ní òru,

      Gbogbo ohun tí wọ́n bá fẹ́ nìkan ni wọ́n á kó.+

      10 Ṣùgbọ́n, ṣe ni màá tú Ísọ̀ sí borokoto.

      Màá tú àwọn ibi tó ń sá pa mọ́ sí síta,

      Kó má lè rí ibi sá pa mọ́ sí mọ́.

      Àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ àti àwọn aládùúgbò rẹ̀ ni a ó pa run,+

      Kò sì ní sí mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́