Jẹ́nẹ́sísì 36:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísọ̀ nìyí: Élífásì ọmọ Ádà ìyàwó Ísọ̀; Réúẹ́lì ọmọ Básémátì ìyàwó Ísọ̀.+ 11 Àwọn ọmọ Élífásì ni Témánì,+ Ómárì, Séfò, Gátámù àti Kénásì.+ Ìsíkíẹ́lì 25:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Màá tún na ọwọ́ mi láti fìyà jẹ Édómù, èmi yóò pa àwọn èèyàn àti ẹran ọ̀sìn ibẹ̀, èmi yóò sì sọ ọ́ di ahoro.+ Idà ni yóò pa wọ́n láti Témánì títí dé Dédánì.+ Émọ́sì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, màá rán iná sí Témánì,+Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Bósírà run.’+
10 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísọ̀ nìyí: Élífásì ọmọ Ádà ìyàwó Ísọ̀; Réúẹ́lì ọmọ Básémátì ìyàwó Ísọ̀.+ 11 Àwọn ọmọ Élífásì ni Témánì,+ Ómárì, Séfò, Gátámù àti Kénásì.+
13 torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Màá tún na ọwọ́ mi láti fìyà jẹ Édómù, èmi yóò pa àwọn èèyàn àti ẹran ọ̀sìn ibẹ̀, èmi yóò sì sọ ọ́ di ahoro.+ Idà ni yóò pa wọ́n láti Témánì títí dé Dédánì.+