Jónà 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ ní tèmi, màá fi ohùn mi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ bí mo ṣe ń rúbọ sí ọ. Màá san ẹ̀jẹ́ mi.+ Jèhófà ló ń gbani là.”+
9 Àmọ́ ní tèmi, màá fi ohùn mi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ bí mo ṣe ń rúbọ sí ọ. Màá san ẹ̀jẹ́ mi.+ Jèhófà ló ń gbani là.”+