Òwe 16:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Orí itan ni à ń ṣẹ́ kèké lé,+Àmọ́ ọ̀dọ̀ Jèhófà ni gbogbo ìpinnu tí ó bá ṣe ti wá.+ Òwe 18:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ṣíṣẹ́ kèké máa ń parí awuyewuye+Ó sì ń làjà* láàárín àwọn alágbára tí wọ́n ń fa ọ̀rọ̀.