-
Àìsáyà 43:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Rán mi létí; jẹ́ ká gbé ẹjọ́ wa wá;
Ro ẹjọ́ rẹ, kí o lè fi hàn pé o jàre.
-
-
Jeremáyà 2:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Ṣùgbọ́n, o sọ pé, ‘Aláìmọwọ́-mẹsẹ̀ ni mí.
Ó dájú pé ìbínú rẹ̀ ti kúrò lórí mi.’
Ní báyìí màá dá ọ lẹ́jọ́
Torí o sọ pé, ‘Mi ò dẹ́ṣẹ̀.’
-