Jeremáyà 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìrora mi pọ̀,* ìrora mi pọ̀! Ọkàn mi* gbọgbẹ́. Àyà mi ń lù kìkì. Mi ò lè dákẹ́,Nítorí mo* ti gbọ́ ìró ìwo Àti ìró ogun.*+
19 Ìrora mi pọ̀,* ìrora mi pọ̀! Ọkàn mi* gbọgbẹ́. Àyà mi ń lù kìkì. Mi ò lè dákẹ́,Nítorí mo* ti gbọ́ ìró ìwo Àti ìró ogun.*+