Jeremáyà 9:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nítorí a ti gbọ́ ohùn ìdárò láti Síónì:+ “Ẹ wo bí wọ́n ṣe sọ wá di ahoro! Ẹ wo bí ìtìjú wa ṣe pọ̀ tó! Nítorí wọ́n ti lé wa kúrò ní ilẹ̀ náà, wọ́n sì ti wó àwọn ilé wa lulẹ̀.”+ Jeremáyà 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó, màá sọ àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà nù bí òkò* ní àkókò yìí,+Màá sì jẹ́ kí wọ́n rí ìdààmú.”
19 Nítorí a ti gbọ́ ohùn ìdárò láti Síónì:+ “Ẹ wo bí wọ́n ṣe sọ wá di ahoro! Ẹ wo bí ìtìjú wa ṣe pọ̀ tó! Nítorí wọ́n ti lé wa kúrò ní ilẹ̀ náà, wọ́n sì ti wó àwọn ilé wa lulẹ̀.”+
18 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Wò ó, màá sọ àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà nù bí òkò* ní àkókò yìí,+Màá sì jẹ́ kí wọ́n rí ìdààmú.”