Ìsíkíẹ́lì 34:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó, èmi fúnra mi yóò wá àwọn àgùntàn mi, màá sì bójú tó wọn.+
11 “‘Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó, èmi fúnra mi yóò wá àwọn àgùntàn mi, màá sì bójú tó wọn.+