-
Sáàmù 74:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Kò sí àmì kankan tí a rí;
Kò sí wòlíì kankan mọ́,
Kò sì sí ẹnì kankan nínú wa tó mọ bí èyí ṣe máa pẹ́ tó.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 13:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Torí náà, ẹ̀yin obìnrin yìí ò ní rí ìran èké mọ́, ẹ ò sì ní woṣẹ́+ mọ́; èmi yóò gba àwọn èèyàn mi lọ́wọ́ yín, ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”
-