Jeremáyà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+
13 “Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+