-
Àìsáyà 60:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ẹni tó kéré máa di ẹgbẹ̀rún,
Ẹni kékeré sì máa di orílẹ̀-èdè alágbára.
Èmi fúnra mi, Jèhófà, máa mú kó yára kánkán ní àkókò rẹ̀.”
-